Ilosiwaju dara. Sugbon Ilosiwaju pe orisirisi. Ilosiwaju lati owo Esu lo po lode oni. Ibukun Oluwa lo nmu ni la lai fi laala si. Esu ki i fun ni ni nkan ko ma siregun. Sugbon Oba a fun ni tan masiregun ko kuro lori ite. Suuru se pataki. Ile aimed laba owo, ile aiye la o fi sile si lo. Oluwa yo gbo adura wa. Ile Yoruba ko ni baje o. Amin.