55. "ìrùkèrè kì í yan ifá lódì; oge, dúró o kí mi."
Update: 2023-02-04
Description
In this episode, host Bidemi Ologunde analyzed the following Yoruba proverbs:
- ìpénpéjú ò ní enini; àgbàlagbà irùngbòn ò se òlòó.
- Irú aso ò tán nínu àsà.
- ìrùkèrè kì í yan ifá lódì; oge, dúró o kí mi.
- ìsánsá ò yo ègún; ìsánsá kì í káwo obè.
- ìsé ò tibìkan múni; ìyà ò tibìkan je èèyàn; bí o bá rìnrìn òsì, bí o bá ojú ìsé wòlú, igbá-kúgbá ni won ó fi bu omi fún e mu.
For questions, comments, or suggestions, please contact the host/producer, Bidemi Ologunde, by email bidemiologunde@gmail.com or on WhatsApp +1-702-983-0499.
Comments
In Channel




