58. "Kàkà kí kìnìún se akápò ekùn, olóde a mú ode è se."
Update: 2023-03-18
Description
In this episode, host Bidemi Ologunde analyzed the following Yoruba proverbs:
- Ká wí ogún, ká wí ogbòn, “Ng ò fé, ng ò gbà,” lasiwèré fi npèkun òràn.
- Kàkà kí àgbò ké, àgbò a kú.
- Kàkà kí bàbá ran omo ní àdá bo oko, oníkálukú a gbé tiè.
- Kàkà kí iga akàn ó padà sehìn, a kán.
- Kàkà kí kìnìún se akápò ekùn, olóde a mú ode è se.
For questions, comments, or suggestions, please contact the host/producer, Bidemi Ologunde, by email bidemiologunde@gmail.com or on WhatsApp +1-702-983-0499.
Comments
In Channel




