ìgbésẹ tó yẹ kí a gbé kí a tó ṣe ìwọ́de (part 2)
Update: 2020-07-17
Description
Èyin olùgbọ́ọ wa, ìtàn ọmọ Nàìjíríà la tún mú wá. Ní ọsẹ́ tó kọjá, a sọ̀rọ̀ nípa àwọn ohun tó yẹ kí á mọ̀ kí a tó ṣe ìwọ́de ìfẹ̀onúhàn. Ní ọ̀sẹ̀ yí, a ma sọ̀rọ̀ lórí àwọn ìgbésẹ tó yẹ kí a gbé kí a tó ṣe ìwọ́de.
Ayodeji Adegbola +2348133871480
Comments
In Channel