ẹ̀sìn àti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
Update: 2020-08-21
Description
Èyin olùgbọ wa, a kúu dédé àsìkò yí...
Ìtàn ọmọ Nàìjíríà la tún mú tọ̀ yín wá.
Lónìí, a ó sọ̀rọ̀ nípa ẹ̀sìn àti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Gbogbo wa la mọ̀ bi ọ̀rọ̀ ẹ̀sìn ṣe pàtàkì ni orílẹ̀-èdè tí a wà yí. Kí ló fàá tí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ṣe rí bó ti wà lónì yí pẹ̀lú bí a ti ń ṣe ẹ̀sìn tó? E ó máa gbọ́ ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ rẹ̀ lórí ètòo tòní.
Ẹ̀bùn gigabyte kan (1000mb) wà fún ẹni tó bá kọ́kọ́ dáhùn ìbéèrè tí ó wà ní ìsàlẹ̀ yí:
*Kí ni ẹ̀kọ́ pàtàkì tí a lè rí kọ́ ni ètòo tòní?*
E fi ìdáhùn náà ránṣẹ́ sí WhatsApp number yí:
+2348133871480
Comments
In Channel